< All Hymns
Print Hymn Lyric

2. Ifẹ Ọrun Alail’ẹgbẹ

ORIN IKEJI ………………………………………..8.7.8.7
Oluwa fi igbala Rv bv mi wo- O. D 106:4

Ifv qrun alail’vgbv,
Ayq qrun sqkalv,
F’aye wa ze ‘bugbe Rv,
D’ade anu otq Rv.
Jesu Iwq n’alanu nla
‘Wq n’fv ailopin mimq
cr Fi igbala Rv bv wa wo
Wqnu qkan vru wa

2 mf Wa, Olodumare, gba wa
Jv ka ri iye Rv gba.
L’ojiji pada, si lailai,
Lai ma fi tvmpil’ lv mq;
f Iwq l’a o ma yin titi,
Sin Q b’ogun qrun nze
Iyin t’adua fun Q titi
Ogo fun ‘fv pipe Rv.

3 mf Z’aze pe awa vda Rv
Jv k’awa lai labawqn
K’a ri titobi ‘gbala Rv
Ka wa ni pipe nu Rv;
ff Ka lq lat’ogo de ogo,
Ta fi d’qrun mu po wa;
T’oa gb’ade wa lv juba Rv
N’iyanu, ifv, iyin. …..….Amin

Previous Hymn 1. Ife Ọrun Alail’ẹgbẹ 2
Next Hymn 4. Oluwa mi, mo njade lọ
Table of Contents

Price Based Country test mode enabled for testing United States (US). You should do tests on private browsing mode. Browse in private with Firefox, Chrome and Safari